
Home / Oro Oselu
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts


Mo tẹ́lẹ̀ wí pé Buhari kò ni òye nípa ètò ọrọ̀-ajé - Obasanjo
"Mo mọ tẹ́lẹ̀ wí pé Buhari kò ni òye to péye nípa eto ọrọ-ajé ṣáájú ko di Aare. Èrò mi ni wí pé, yoo se àmúlò àwọn ènìyàn ọlọpọlọ tí wọ...
Read More

Kilo mú àwọn gómìnà Nàìjíríà rọ lọ siluu Abuja lana?
Àwọn gómìnà káàkiri tibutoro orileede yìí ni wón gbara jọ sí ìlú Abuja lana, 17-01-2018, láti jíròrò lórí àtúnṣe ìwé òfin Nàìjíríà àti àwọn ...
Read More
Orí akitan ni wọn ti bá òkú ọmọ ilẹ̀ igbimo asofin tí wọn jigbe
Onarebu Hosea Ibi ọkàn nínú àwọn ọmọ ilẹ̀ igbimo asofin ipinle Taraba tí wọn jigbe ni Dec 30, 2017 ni wọn ti padà rí òkú rẹ lórí akitan báyì...
Read More

Saraki @55: Ẹja ńlá tí ń danu odò ru gbudugbudu
Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, pé ẹni ọdún márùn-ún-le-ni-aadota (55) lojo Isegun to koja yii, 19/12/17. Aimoye awon ènìyàn n...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)