
Iku Bola Ige Dapagbe? Mo gbagbe apileko mi sile lonii. Ohun ti mo ti lero wi pe maa wi gan-an mbe ni yewu mi. Sugbon bi mo tile mu un dani, o daju wi pe mi o ni gbe safefe fun gbogbo ero to setan lati ka iroyin mi. Idi aba ni wi pe ero ti gun ori ero fun mi. Alaye mi si ti gbomo pon lori ara won. Olayemi, ibeere lasan ni mo fe beere ki n si pada si yemu mi. Se ka gbagbe iku to pa Bola Ige ni? Ore ti pe asiwere eniyan ti gbagbe patapata. Iwa ibaje o jowa loju mo aye tun daso bo iwa ika mole. Bi o tile je wi pe eni to ti ku o ni pada wa ile aye mo, sugbon ika eniyan to ku ko ni i ye sapa gangan lawujo awon eniyan atata. Se ka gba wi pe apagbe niku Bola Ige ni?
0 comments:
Post a Comment