?
Baba alawo to sogun afeeri fayan naa lo se arinako fadiye. Olori olopa yan-anyan ni ile yii, Oga Agba Muhammed Abubakar ti kede wi pe owo ti te awon onise ibi ti won da emi komisanna ipinle Kwara legbodo, iyen ogbeni Chinwike Asadu eni ti won seku pa ni ojo keta osu keta odun taa wa yii (3-3-13) ni Ipinle Enugun.
Awon eniyan meje ti won fura si naa ti wa nibi ti won ti n fi kerosin mu gaari lowolowo bayii ki eto idajo won to wole de.
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment