Smiley face

AMAECHI JAWE OLUBORI

Gomina ipinle Rivers, Gomina Chibuike Amaechi pada wole eleekeji gege bi olori igbimo awon gomina orile Naijeria lapapo.

Ninu eto idibo to waye ni ojo Eti (24-5-13) ni ilu Abuja, nibi ti Gomina Amaechi ti jan eyin akegbe re to wa lati ipinle Plateau, Gomina Jonah Jang mole ti o si le dide nile mo rara pelu onka idibo okandinlogun(19) si merindinlogun(16).

Gbogbo gomina to wa ni jakejado ile Naijeria pata lo pese sibi eto idibo naa ayafi gomina ti ipinle Yobe ti a gbo wi pe ko wa sibe eto idibo naa rara

Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment