Ojo gbogbo ni tole, ojo kan ni tolohun. Owo ti te osise meji ile ise oko ofurufu Arik Airline ni ilu london pelu esun wi pe won gbe ogun oloro wole lati ilu Naijeria.
Ogun oloro ti won so wi pe iye re din binti ni Ogorun Meji Milionu Naira ni awon ajo NDLEA ile Naijeria ti bere ise iwadii le lori nigba ti awon osise meji ti won mu sile si wa lori iso ni ilu London.
Olayemi Olatilewa. E-mail olayemidakewi@hotmail.com, Phone:0803 239 4964, PIN 28EEEAE2
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment