Owo awon olopa to wa ni Ikeja ni ilu Eko ti te awon amookunseka merin kan ti won tu eya ara awon oku ta bi paati oko.
Awon onise ibi yii ni won si ti bere si ni i ka boroboro gbogbo ibi ti won n ta oja won si nigba ti kondo awon olopa wo won ni akinyemi ara.
Okan ninu awon ti owo te ti oruko re n je Agboola Kolawole so wi pe ori oku kan ti awon ba wu egberun mejo ni awon n ta(8,000) apa ni egberun merin (4,000), oju ara eniyan ni egberun mewa (10,000).
Lara awon ti owo tun te ni okunrin onisegun kan ti oruko re n je Rafiu Ajibade, gbogbo won pata lo wa ni sago awon olopa yato si okan ti a gbo wi pe o fiku se ifaje nigba to n gbiyanju ati jajabo lo awon olopa ko-gbe-regbe nigba to be sile ninu oko to n saa lo.
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment