Ogbontarigi Agbaoje agba boolu agbaye omo Naijeria, J.J Okocha se afihan aworan re ni eni omo odun meta lati yayo ayajo awon ewe to waye ni ojo ketadinlogbon osu karun-run odun yii. Bakan naa lo tun gba awon ewe ni imoran lati wa okun ati agbara lati le mu ala won se.
0 comments:
Post a Comment