Lori oke ọkan yii naa ni.Sáájú ko to dohun àjíkì.
Sebi won ni bọmọde kò bátapàn.
Àtìtàn atarọba le mi yan bi ẹran lórí atan.
Sekaseka boo ba leti gbọ mi loni.
Aya koko inaki, alayaa bi esu.
O n sebi won sàà ọ o tun dun nú.
Lori oke yii naa ni.
Jagilegbo soogun joojumọ nisẹ ibi.
Oró dídá ni fi n sọla.
Baba ologun ìkà ti won pe Kògbebọ.
Ada ò ran, ibọ ọ ran bẹẹ ni i daye laamu tiyọnutiyọnu.
Ori oke ọkan yii naa ni.
Nibi o ti n jáwé amuseka.
Kogbẹbọ yẹgẹrẹ ẹsẹ lo ba fori n'apata.
Gbogbo purapita apa ba pin.
Ewo bi Ọba oke gba mu ika eniyan.
Isu dilẹ leyin asunsu jẹ
@dakewi
@dakewi
ReplyDelete