Smiley face

Gbogbo Ilu Gbadura Fun Mandela

Gbogbo ara Ilu South Africa ti gbe ebe adura soke si Olorun oba fun Nelson Mandela, eni ti o ti lo to ojo meta bayii ni ile iwosan latari aisan ona ofun to n yo lenu.
Olayemi Olatilewa
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment