Smiley face

Buhari Fesun Kan Oritsejafor

Ajagun feyinti to tun je olori orile Naijeria fun igba kan ri, Muhammadu
Buhari ti fesun kan olori ajo awon omo leyin Kristi ile yii (Christian Association of Nigeria), Oluso Aguntan Ayo Oritsejafor wi pe o n kona mo iyansipo Aare Goodluck Jonathan fun igbakeji.

Eleyii waye latari atejade kan eleyii ti Oluso Aguntan Ayo ti n so wi pe Buhari ni Baba Isale awon obayeje ti won pe ni Boko Haram ati wi pe ki ijoba apapo so si gbaga awon agbofinro.
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment