Lojiji ni ina tun seyo lana ojo isinmi (9/6/13) ni oja Trinity ti won ti n ta eya ara oko ni agbegbe Olodi Apapa, Ajegunle. Aimoye dukia la gbo wi pe o jona wuruwuru latari ina monamona(PHCN) ti won mu de ni nnkan bi ago kan osan.
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment