Awon omo ogun agbesunmomi ti a mo si Taliban meje ni won ti dohun igbagbe nibi itaporogan to waye laaro ojo aje (10/06013) ni ilu Afghanistan.
Ija ajakuakata to waye ni ibi ile-alaja-marun-un kan ti won ko ti i kotan ti ko jina si papa oko ofurufu ni Kabul ni awon omo ogun Afghanistan lo ka won mo ti won si beere si ni i da ota ibon sile bi agbado yanga.
Bi o tile je wi pe ija naa ti dawo duro bayii, sugbon ile ise asoju ile Amerika ati tile Biritiko ti a mo si Embassy ti ko jina sibi isele naa la gbo wi pe won ti gbe ilekun ti bayii ti onikaluku si ti gba ile re lo. Sebi eni Sango ba toju e wo le ni, koni ba won bu oba Koso.ò
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment