Smiley face

Won Ti Gba Ohun Amusagbara Boko Haram

Awon Yoruba loni ki ile to pa osika, aimoye ohun rere ni yoo ti segbe danu. Adura wa ni wi pe ki ibi maa se de ba wa mo ni ile yii titi owo yoo fi te gbogbo awon amokunseka.

Awon olopa digboluja ti won mbe ni ilu Kano ti se awari ibi ti awon omo alakatakiti esin Boko Haram ti n se ado oloro. Orisiirisii eroja kemika ati ohun elo ti won fi se agbelero ado oloro ni iroyin fi to wa leti wi pe won ko ninu ibuba won.

Ekunrere alaye mbo laipe.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment