Ise orin kiko, ajumose ni. Yato si wi pe Gbenga Ojoyido n te jita fun Ayelefe, oun kan naa ni olootu orin re ti ma n ba to gbogbo alujo orin ati ilu papo to fi n dun leti araye.
Awon Yoruba si ni ti oba kan ko ba ku, oba mii ki i je. Gbenga Ojoyido ko ku, Jagunlabi salo leyin Ayefele ni ilu Amerika ni.
Nibayii, Ayefele ti yan olootu orin re tuntun, Shadare Agboola ni oruko okunrin naa nje. Oun kan naa ni o si maa ba ise lo gege bi akosile kadara Marry Makers.
Aworan: Shadare Agboola
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
Haaaaaaaaaaaaa, awon eleyi bad gannn ni
ReplyDeleteOº°˚˚˚°º .
Olorun a ba e se o @agboola.
ReplyDelete