Eto ifowopamo ile Naijeria tun setan lati goke agba sii pelu ilana tuntun eleyii ti banki agba ile Naijeria kede wi pe ika tite ni awon eniyan yoo maa lo lati fi gba owo ni banki gege bi amin idanimo.
Eyi ni wi pe awon kaadi idanimo eleyii ti aworan onibara n se apeere amin idanimo ti a ti fi n gba owo tele yoo di ohun afiseyin ti eegun fi aso.
Osu keji odun 2014 ni ilana tuntun yii yoo bo si oju ise.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment