Smiley face

DSTV Ti Si Gbogbo Telifisan Re Sile Lofee Fun Ose Kan Gbako


Iroyin ayo fun gbogbo awon onibara DSTV, ile ise naa ti si gbogbo amohunmaworan won sile fun ose kan gbako lofee fun gbogbo awon onibara won.

Odoodun ni won maa n se eleyii. Ana lo bere, ose kan ni ilekun yoo si fi si sile gbayawu.

E ku igbadun oteyi!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment