Iyalenu lo je nigba ti Foluke Daramo so ni gbangba wi pe oun ko le fi oko oun sile, koda ko je wi pe o fun obirin mii loyun sita.
"Pupo awon eniyan ti won je ayanfe Olorun ninu bibeli ni won ni ju iyawo kan lo. O se mi laanu fun iyawo oko mi tele to ko o sile tori wi pe Kayode n yan mi lore. Bi Kayode ba tun gbera lo maa wu awon iwa ti mi o fe ti mo wa ni mi o fe mo, ta lo padanu?. Mo nife oko mi, ko si si ohun to le ya awa mejeeji' Foluke Daramola
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment