Smiley face

Idasesile ASUU N Lo Sopin

A ti n gbo finfin wi pe oseese ki awon omo egbe ASUU fagile iyanselodi ti won ti gunle bi osu bi melo kan seyin ni Ojobo ti n bo yii.

Awon egbe yii ni won tun fe se ipade po pelu ijoba apapo ni Ojoru ose yii kan naa, opolopo si n ro wi pe oseese ki ipade naa yanju gbogbo oro laaarin iko mejeeji.

To ba le ri bee, sebi ope ni aa ba du lowo Yaradu loke.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment