Prince Nwafor, ogbologbo ole eni odun metalelogun ti owo awon olopa te ni ilu Eko ni won ri pelu bi o se n ya fidio bi won se n ja moto gba loju popo si ori foonu re. Awon olopa bi nipa kini idi ti o fi n ya awon fidio naa pamo.
"Tori awon ti mo n ba sise ni o, ojokijo ti won ba fe dale mi nipa owo pinpin, mo pinnu lati tu won lasiri' Prince
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment