Leyin ose kan ti iku pa olori ile igbimo asofin Ipinle Taraba eleyii ti iwadii si n lo lowo nipa iku to pa oloselu naa.
Awon amokunseka kan tun gbiyanju lati pa igbakeji re, Adamu Tanko Maikarfi sugbon ohun ti okunrin naa je tele ikun ko je ki won ri mu.
"Ile egbon mi ti mo wa ni won wa ka mi mo. Oro naa si dabi eni wi pe won ti ri eni se alami fun won ni. Sebi ti ina ko ba lawo ki i goke odo. Gbogbo inu ile ni won wa, sugbon mo dupe lowo ori mi ti ko fi mi le ota lowo" Adamu Tanko Maikarfi
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment