"Ohun to daju ni wi pe igba iponju laa more. Eni duro tini lojo ogun le ni alabaro eni. Lonii, ife kan soso ti mo ni mu mi lo sodo lowe. Eni ti mi o le ko ohun si lenu. Eni ti mo nife denudenu. Ki lo fe se mi ti mi o ni fe e? Laye igba ti mo n wa okada, oun naa ni. Atewo nla ati ariwo fun ololufe mi. *chop1kiss*" Olamide
Olamide Se Afihan foto ololufe re, Aisha Sulaiman pelu akole oke yii. E ri wi pe ife otito a maa n dun pupo?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment