Smiley face

"Awon Awako Akero Ilu Eko Yoo Bere Si Ni Wo Aso Egbejoda Bere Lati Odun 2014" -Komisanna

Komisanna fun Eto Irina ti Ipinle Eko, Ogbeni Kayode Opeifa ti salaye wi pe gbogbo awako akero ati kondokito ti mbe ni Ipinle naa yoo bere si ni wo yunifoomu ati baaji-aya fun idanimo bere lati odun 2014.

Eko o ni baje ooo!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment