Smiley face

Mercy Aigbe Se Igbeyawo Kootu Pelu Ololufe Re Leyin Igba Ti Won Ti Bi Omo Kan Fun Ara Awon

Mercy Aigbe pada se igbeyawo pelu oko re, Lanre Gentry lana ode yii ni Ikoyi registry to wa ni ilu Eko.

Bi igbeyawo yii se je eleekeji fun Mercy Aigbe bakan naa lo je igbakeji ti Lanre Gentry naa yoo maa se igbeyawo.

Mercy Aigbe ti bi omo kan tele ninu igbeyawo re akoko bakan naa lo si ti bi omokunrin kan fun Lanre Gentry naa pelu.

Bi o tile je wi pe ayeye igbeyawo naa ko pariwo sugbon awon ologbon aye je ko ye wa wi pe adun ati ayo igbeyawo kosi ninu ayeye ati ariwo lasan.

Gbogbo wa la ba Mercy Aigbe yo!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment