Bi o tile je wi pe odun n lo sopin eleyii to mu awon agba osere kan lo fun isinmi odun, sibesibe awon kan o dawo ise duro lati te awon ololufe won lorun.
Mercy Johnson ko lati lo fun isimi, ti iresi to gbe kan na ba jinna tan gbogbo aye ni o buje nibe.
E ku oju lona!
Mercy Johnson ko lati lo fun isimi, ti iresi to gbe kan na ba jinna tan gbogbo aye ni o buje nibe.
E ku oju lona!

0 comments:
Post a Comment