Smiley face

Ile Oge Ati Ewa To Lekenka: Doris Simeon Ti Si Davris Beauty Centre Si Ilu Eko



Doris Simeon si ile isara loge re to pe ni Davris Beauty Centre to wa ni Ogba ni ilu Eko lana ojo Eti (20/12/13).

Aimoye ore ati ololufe ni won pajo lati fi idunnu won han nipa aseyori oserebinrin naa.


 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment