Smiley face

Oro Agba Lati Enu Osita Iheme (Paw Paw)


Bi o tile kere loju, gbogbo aye ti mo wi pe ki i somode, agbalagba ni. Awon Yoruba si bo, won ni oro agba bi kose lowuro, dandan ni ko se lojo ale.

Osita Iheme ti gba awon omo ile iwe lamoran lati gbajumo eko won. Gege bi oro re, oni eko nikan lo le mu ni de ipo giga ati wi pe ogun ayeraye loje fun awon ewe iwoyii ti won ba le farabale lati keko to ye kooro.

Irawo osere yii lo se agbekale oro yii nigba ti o n pin ebun fun awon akekoo to pegede ninu idije " Tan N Mo?' eleyii ti Osita Iheme Foundation se agbeteru re.
 


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment