Smiley face

Kunle Afolayan Se Igbeyawo To Fakiki

 
Beeni o, bi mo ba ni Kunle Afolayan se igbeyawo to fakiki ki i se iro rara. Bi o tile je wi pe inu fiimu Tunde Kelani ti won n ya lowo ti won pe akole re ni 'Dazzling Mirage' ni Kunle ti sodun ife pelu Kemi Lala Akindoju.

Ninu fiimu yii kan naa ni baba to bi agbaoje olootu ise orin kiko, Don Jazzy ti kopa gege bi baba Kunle Afolayan. Ireti wa ni wi pe odun 2014 yoo woran ayo nigba ti fiimu naa baje.

Bakan naa, opolopo awon onwoye ise opolo ti sakiye wi pe oseese ki fiimu 'Dazzling Mirage' je okanlawon ninu awon fiimu ti yoo foju han ninu odun tuntun to wole de tan yii.
 E ku oju lona!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment