'Bi ohun kan ba se pataki si mi lasiko ti mo wa yii, ise mi ati aye mi ni...e gba bee...walaahitalaahi. Bi enikan ba ro wi pe oruko re ti mo n je ni mo fi n gba star tabi ohun ni aye fi mo mi, e ba mi so fun wi pe ko gbagbe bo se sele ooo{fathia bu serin}, ise oluwa ko dawo duro menn.'
Fathia Williams ti gbogbo eniyan mo si Fathia
Balogun tele ni o fi oro yii sawada laaarin awon akegbe re ti won rogba yika ni Ipinle Oyo nibi ti o ti n ya fiimu re tuntun lowo eleyii ti yoo jade lodun 2014.
Oludari fiimu naa ni Abbey Lanre nigba ti Tope Bello je oluranlowo fun Oga Lanre. Orisiirisii osere naa ni won wa pelu re, awon bi Odunlade Adekola, Dayo Amusa, Funke Etti, Adebayo Salami ati bee bee lo.
E tesiwaju lati wo awon aworan to ku.....
FATIA ,TI ENYAN BA TI PASE EKAN GUN OKE LAIYE ,OLUWA LOFUNSE ,BEYI OSE ELOMIRAN O YOSE. .GBAJUMO ISE OWORE ,OLUWA OLORUN TI O DAAYIE YIO TUN MU O LO SI BI KIGA JU BAYI LOOOO.
ReplyDeleteBeeni oo. Ibi ti eniyan maa de, dandan ni yoo de bee. Ati wi pe oro ololufe meji ko see dasi. Ki oba Oluwa saanu fun gbogbo wa
ReplyDeleteoro oko pelu iyawo oju oluwa lo le to
ReplyDelete