Ile ise iroyin Guardian ti Ilu Oba Biritiko ti kede awon Ogorun agbaboolu to fakoyo ju lo fun odun 2013 to setan lati kogba sile yii.
Idunnu awon ololufe ere boolu Naijeria si ni lati ri ka wi pe Emmanuel Emenike to je omo egbe agbaboolu Super Eagle ati Fenerbahce naa fara han ninu akosile naa.
Ipo ketadinlogorun (97th) ni agbaboolu to gba ayo merin wole fun ile Naijeria ninu idije African Nation Cup todun 2013 gbe.
Ireti wa si ni wi pe Emmanuel Emenike yoo tun bo jo aye loju ninu idije agbaye ti yoo waye lodun to n bo ni ilu Brazil.
Olayemi Oniroyin, ibi ni maa ti maa danu duro fun abala ere idaraya.
E ku imurasile odun!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment