Awon eniyan bi merin ni won koja lo sorun lesekese, aadorin farapa yannayanna, awon bi mokanla si wa lese kan aye, ese kan orun ninu Ijamba oko oju irin to waye ni New York laaro putuputu ojo aiku to koja yii (1/12/13).
Oko oju irin yii lo ye gere kuro ni oju ona re nigba to fe seburu ona ti gbogbo re si yikata danu sinu igbo.
Awon alase tile so wi pe aimoye emi eniyan ni ko ba sonu to ba je wi pe ojo ise ni isele naa se, nitori wi pe ero oko naa a maa kun lojo ise yato si opin ose lo.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment