Ori ero twitter ni Toyin Aimakhu ti fa ibinu yo, enikeni ko si le so nipa eni to n paroko oro ranse si. Bi o tile je wi awon ololufe re n bere lowo re wi pe taa ni agbaya na to un ba wi, eleyii ti ko da esi pada. Eyin naa e ka awon oro re boya e le ni oye eni ti o n soko oro si.
E tesiwaju lati ri awon oro ti Toyin ko.......
O ga ju!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)

0 comments:
Post a Comment