Mo ti kede fun yin nipa omokunrin dudu to pada di pupa eleyii ti o salaye ara re gege bi onise oge ti n ta ogun eleyii to le mu eniyan dudu di pupo.[E ka iroyin naa nibi] Lara alaye re ni wi pe ara bibo ti oun n bo, ipolowo oja ni oun fi se. E ja ka tun wo die lara awon aworan tuntun ti omokunrin naa tun fi si ta.
E tesiwaju lati wo awon aworan to ku......





0 comments:
Post a Comment