Ohun iyalenu sele lonii ni Jeddah nigba ti won ri ajaku ara omo eniyan to jabo sile lati oju ofurufu.
Nikete ti won ri ohun ajoji yii ni won ke si awon agbofinro.
Iwadii awon olopa si fi ye wa wi pe oseese ko je ajaku awon eniyan ti won sawo abe baalu Ilu Saudi Arabia to gbera lati ilu Iran ni ona ati wo inu ilu wa nipa ogbon alumonkoroyi eleyii to ja si iku ojiji fun won.
Gege bi iwadii wa, a ri gbo wi pe iru nnkan bayii ti sele ri ni odun 2010 ti won ba oku eniyan nibi palapolo ese baalu ilu Saudi to ti gan bi eje kote eleyii ti won ri nigba ti baalu naa ba sile.
Iwadii si n lo lowo lati mo okodoro oro, ati awon nnkan to farasin nipa isele kayeefi yii.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
Eniti o nwa ifa, ofo lonwa.
ReplyDelete