Calabar Carnival 2013.Calabar Carnival
Akojopo awon aworan odun ijo, orin ati igbelaruge asa ile adulawo to maa n waye lodoodun ninu osu kejila ni Ipinle Cross River, Nigeria.
Ti Odun 2013 tun kamomo, e tesiwaju lati wo awon aworan ohun to sele nibe...
0 comments:
Post a Comment