Smiley face

Aso Funfun Gbayi Lojo Ti Jide Kosoko Se Ayeye Ojo Ibi Re


 
 Leyin ti Jide Kosoko pe eni Ogota odun laye, Yinka Ayefele pada da ariya sile lana ode yii ninu gbongan nla kan to wa ni Ile Orin Yinkan Ayefele to wa ni ilu Ibadan. Ebi, ore, alabasise ati ojulumo ni won pejo lati ba Omo Oba Jide Kosoko yo fun ori ire nla to se.







 
Awon foto to ku n bo laipe.......
 
 
 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments: