Smiley face

Toko-Taya N Ba Ara Won Sun Nita Gbangba



 
Awon Yoruba so wi pe were dun un wo loja ni ko se e bi lomo. Edumare ma je ki buburu kan wa. Awon toko-taya were meji yii ni won sadeede n ba ara won sun ni ita gbangba ni ilu Ghana. Gbogbo eniyan ti n koja lo ba tasa duru lati wo fiimu ofe.
 




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment