Sebi baa se bi eru, la se bi omo. Oni la ri, Edua oke nikan lo mo ile ti mola. Bi o tile je wi pe ko wopo ninu awon irawo osere lati maa se afihan ife won si awon eniyan ti ko to won sugbon ti won sun mo won bi isan orun. (Olowo n sore olowo ni opolopo won n se)
Igba akoko ko re ti Tonto Dikeh yoo maa soro nipa oluranlowo re ninu ile, eleyii to si n se apejuwe bo se nife omo naa si. Onyinye lo pe oruko omo na, awon mejeeji si jade lopin ose to koja yii lati lo je kugu aye lese odo.
![]() |
Onyinye n jaye bi Oba Lamide |

Ba a Se Bi Eru, La Se Bi Omo |
0 comments:
Post a Comment