Smiley face

Aworan Mi Leyin Ojo Kewaa Ti Mo Bi Omo Mi - Kaffy Omo Onijo


 
Sebi igbe kike nise eye, aroye nise ibaka. To ba ti je tijo pakaleke, Kaffy Omo Onijo setan ni gbogbo ojo ni. Leyin ojo kewaa ti Kaffy ti dide ikunle omo bibi, o dabi eni wi pe omo onijo naa ti n mura ati pada senu ise re.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment