
'Esu ko ni fa foto mi ya,
Omo ti mo bi ni foto ti mo ya,
Esu ko ni fa foto mi ya.'
Agbaoje agbaboolu omo Naijeria, Osaze ti ranse ikinni si gbogbo awon ore ati ojulumo ti won pejo si bi ayeye ojo ibi akobi omo re to waye lana. O tun fi dawon loju wi pe ti yoo ba fi di osu kefa odun yii, iyawo oun Sarah Fallon yoo tun ti bi omo tuntun ti o je bi aburo fun eyi ti awon n se ojoibi fun.
0 comments:
Post a Comment