Smiley face

Michelle Obama Pe Eni Aadota Odun Laye: Okiki Awon Eniyan Dudu Ni Ile Amerika Ati Agbara


17th January, 1964
Ojo Ketadinlogun Osu Kinni Odun 1964 ni won bi Michelle LaVaughn Robinson Obama ni ilu Amerika. Ilu Chicago ni won bi si, ibe naa lo ti se olomoge.
 
 
Ifafiti Princeton lo ti ko nipa idagbasoke ati ihuwasi awon eniyan awujo ati orirun awon eniyan dudu ni ile Amerika ko to lo ko nipa Imo Ofin ni ile iwe ti won ti n ko nipa ofin ti Harvard. Onkowe ni Michelle, agbejoro to gbamuse si ni pelu ti ori re si pe perepere bi alajo Shomolu.
 
 
Oko mi chop noku, ori won o si n be..
 
Oun kan naa si lo je iyawo Aare ile Amerika eleekerinlelogoji (44th) to ti gori oye. Odun 1992 lopinnu lati je aya Barack Obama. Michelle si feran ko maa se apejuwe ara re gege bi  Iya  Malia ati Sasha eleyii to n se apere ayo ati idunnu ti Edumare ti fi si ipinnu re to se lodun 1992.
 
 
 
Oro enu re akin ni, ogbon ori re erujeje ni. E maa pe Michelle ni obirin lasan, sebi o wu Edumare lo se ori ewa fakuko. Bi o ba si Michelle, o seese ki Barack Obama ma je Aare 'Olori Aye'. Michelle pe eni aadota odun lonii (50years), gbogbo aye ni won gbedi soke fun obirin to ju obirin lo..
 
 
Michelle Obama ni Odun 1971
Odun 1992 la se igbeyawo won

 
Awon oro enu Michelle Obama:
 
'You may not always have a comfortable life and you will not always be able to solve all of the world's problems at once but don't ever underestimate the importance you can have because history has shown us that courage can be contagious and hope can take on a life of its own.'
 
 
'One of the lessons that I grew up with was to always stay true to yourself and never let what somebody else says distract you from your goals. And so when I hear about negative and false attacks, I really don't invest any energy in them, because I know who I am.'
 
 
We learned about honesty and integrity - that the truth matters... that you don't take shortcuts or play by your own set of rules... and success doesn't count unless you earn it fair and square.
 
 
'I never cut class. I loved getting A's, I liked being smart. I liked being on time. I thought being smart is cooler than anything in the world.'
 
Happy Birthday!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment