 |
Nino ati Sunmbo |
Bi o tile je wi pe 2fece Idibia ko ni n se oko Sunmbo mo bayii (omobirin naa ti ni oko miiran), ohun to so won po ti di itan ti ko le parun lailai. Sunmbo Ajaba lo bi akobi omo fun 2face, Nino Idibia eleyii to pe omodun mejo to si je idunnu nla fun baba re ti ko si le e pa a mo ra. Tuface ti ranse ikinni si omo re, o se se apere omo naa gege bi okan lara Ogo aye oun.
 |
Nino Idibia : Omo Ajanaku |
 |
Ajanaku gangan |
0 comments:
Post a Comment