Agbaoje omobrin olorin takasufe ile Amerika, Rihanna ti lo si ilu Brazil lati lo ya orisiirisii aworan leti odo fun Magasiini agbaye Vogue eleyii to je akanse fun ilu Brazil. Opolopo aworan alarambara ti omoge naa ya lo je wi pe ko wo aso sara, leyin wi pe o kan ja ewe kekere kan bo ori oyan re. Oluya to ya foto Rihanna naa se ise takuntakun gan-an ni o. Bi Rihanna se n yodi sotun, to tun un yodi si apa osi bee naa ni oluya n gan ni foto parapara.
0 comments:
Post a Comment