Smiley face

9ice Setan Lati Gbe Apoti Idibo Lodun 2015 : Gongo Setan To Fe So



Okunrin Ogun
Abolore Akande(9ice) ti kede lori ero instagram re lati gbe apoti idibo lati soju Ekun Arewa Ogbomosho(Ogbomosho North Constituency) gege bi Onarebu lodun 2015

 
 
Ojo ketadinlogun osu kinni odun 1980 ni won bi Abolore Akande si ile aye (17th of January 1980). Bo se lo si ile iwe alakobere Abule Okuta bee naa lo lo si CMS Grammar School ni ilu Eko. Omo Ogbomosho ni 9ice ni Ipinle Oyo, Sugbon Bariga ni Ipinle Eko lo dagba si. Omo Akekoo Imo Ofin ni 9ice ni ile iwe Ifafiti ti Ipinle Eko(LASU), Sugbon opolopo orin ti n ja lori re ko je ko duro kawe tan to fi lo bere ise orin kiko. Sugbon o tun pada lo ka eyi to ku ninu eko re nigba owo ati okiki de. 



Awon awo orin ti 9ice ti se jade:
  • Certificate (2007)
  • Gongo Aso (2008)
  • Tradition (2009)
  • Versus (2011)
  • Bashorun Gaa (2011)
  • Deluxe Version Versus & Bashorun Gaa (2011)


Awon Ami Eye to gba lagbo amuludun ise orin kiko
  • MOBO Best African Act 2008
  • Nigerian Music Awards Best Act 2008
  • Nigerian Entertainment Awards Most Indigenous Act 2007
  • Nigerian Entertainment Awards Best Act 2008
  • Future Awards


Awon Ami Eye ti awon ile ise amohunmaworan fi da lola.
  • MTV Base Best Hiphop Act 2008
  • LTv/Eko Fm Awards


Awon Ami Eye to gba lowo awon Magasiisini ti won se agbeteru fun amuludun ati ise orin kiko:
  • Hiphop World Awards Best Vocal Performance Male 2008
  • Hiphop World Awards Revelation of The Year 2008
  • Hiphop World Awards Best Album 2009
  • Hiphop World Awards Best Act 2009
  • Hiphop World Awards Best Song 2009
  • Dynamix Awards Most Promising act 2007
  • Dynamix Awards Best Song of The Year 2008
  • Gbedu Awards 2008
  • City People's Award 2009
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment