Ọmọ Ile Igbimọ asoju-sofin, Abike Dabiri Erewa ti koro oju si bi Aare se yọ Lamido Sanusi loye gẹgẹ bi olori Banki apapọ ile yii lai gba atilẹyin awon ọmọ ile igbimọ Asofin. O ni igbesẹ naa tako ofin ilẹ wa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
Won fe bere lati ja naijiria lole gan niyi bayi. Emaje ki ntanyin kosi nkan to nje ibo ni odun 2015 awon igbo fe dawa GEJ si nwa ona lati je kojepe gbogbo nkan toje oroaje gbogbo naija awon igbo ni gbogbo e majamon lowo. Enugu ni mowayi mosi ni anfani lati ba okan lara omoogun masob foro jomitoro oro kokuku mon pe omo yoruba nimi omo igbo totipe nile okere lopemi
ReplyDelete