Rihanna ni oun ò pe èrò rara, iwọnba awon ọ̀rẹ́ afẹnifẹre lasan lo pe si ile rẹ to wa ni Aspen ni Colarado nibi to ti se ayẹyẹ ọjọ ibi odun mẹrindinlọgbon(26) rẹ to wa ye lana. HBD
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment