Alessandra Ambrosi pẹlu irun alárà oge nibi ayẹyẹ Vogue Carnival to waye lỌjọ́bọ̀ to koja. Kókó iroyin awon oniroyin oge sise ni àkókò to gba omobirin onise oge naa lati se irun rẹ lọ́jọ̀ eleyii ti won gba wi pe o jẹ oju nigbese.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment