Ohun ti oju Sanusi ri lonii, titi aye ni yoo maa royin ọwọ́ agbara ti won fi gba loju eleyii to n mu oju rẹ pooyi bi síabábà.
Lẹyin ti Aare ti kede iyọloye rẹ. Sanusi Lamido n daribọ lati ilu Niger Repulic nibi to ti lọ se ipade pẹlu ajọ ECOWAS. Gẹgẹ bi ile ise iroyin Sahara Reporters se salaye, won ni awon osisẹ alaabo kọkọ gba iwe ìrìnnà Oga Banki Agba ile Naijeria nigba kan ri nikete to fẹsẹ balẹ ni papakọ ofurufu Muritala to wa ni ilu Eko ti won si ni ko maa lọ lọwọ ofo ki Jagunlabi to fara ki wi pe oun ki i se ọdaran. Aimoye awọn eniyan ni won kọwọ rin pẹlu Lamido. Ara won ni Iyawo rẹ ati Mallam Nasir El Rufai.

0 comments:
Post a Comment