Sebi nidi ise eni lati n moni lole. Osupa oba orin lo si kilo fun
gbogbo aye wi pe ki won yee pe awon onise tiata lalagbe mo nitori ise
opolo to kun fofo ni ise won.
Lara awon aworan ise sinima ti Ini Edo n se lowo niyii. Ka si ma paro, asaraloge to pa oju orekelewa yii da gbiyanju koja die.
0 comments:
Post a Comment