
Ojo ti n pagun ojo ti pe. Ojo Aboki ti pe n Sabo ona ti jin. Gbajugbaja ile ifowopamo ti a mo si First Bank ti pe ogofa odun (120yrs) ti won ti da sile.
E gbo ohun ti oga agba agbarijo ile ifowopamo naa, Mallam Bello Maccido so.
"Our story is a story of humble beginnings- from a small bank with a paid up capital of £12,000 to one of the most enduring African brands. We have seen the Nigerian public through the turn of two centuries and even a new millennium. Our story is the story of Nigeria and the Nigerian people," lati enu Maccido, CEO FBN Holdings.
Gbogbo wa la ba First Bank yo fun aseyori ise akoni.
0 comments:
Post a Comment