Emi ti mo lati ojo to ti pe wi pe igbe aye eda nipa aso wiwo ati oge sise mbo nibi ti eniyan ko ni lero lailai.
Ni aye igba kan, ti omobirin ba wo sokoto (sokoto gidi to bo gbogbo rara), iran ni gbogbo eniyan yoo maa fi iru obirin bee se nitori wi pe ohun to se ajeji ni awujo wa ni.
Igba to tun ya, bebere idi ni won tun gbe sokoto si lai wo awotele.
Ibi ti oge sise tun wa de duro bayii tun wa koja afenu so, eyin naa e wo enu ile ke e wo enu oko.
Se idagbasoke n de ba oge sise ni tabi radarada?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment